Ǹjẹ́ fífi tipátipá fa òjò ló fa omiyale ní Dubai?

  • 📰 thecableng
  • ⏱ Reading Time:
  • 78 sec. here
  • 3 min. at publisher
  • 📊 Quality Score:
  • News: 35%
  • Publisher: 80%

Nigeria Headlines News

Nigeria Latest News,Nigeria Headlines

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ atẹjade lórí àwọn ohun ibaraẹnise ìgbàlódé ti sọ pé òjò arọfẹku tàbí òjò omiyale, èyí tó rọ̀ tó kówàhálà bá àwọn ará orílẹ̀-èdè United Arab Emirates (UAE) ṣẹlẹ̀ nítorí pé wọ́n fi kẹ́míkà wá òjò tipátipá.

Ọ̀rọ̀ yìí, tí ó wà lórí X, ohun ìgbàlódé ibaraẹnise tí a mọ̀ síTwitter tẹ́lẹ̀, Facebook, ohun ìgbàlódé ibaraẹnise lórí ayélujáraàti Instagram, ohun ìgbàlódé ibaraẹnise tí àwọn ènìyàn ti máa ń pín àwòrán nǹkan tàbí ti ara wọn, fihàn pé UAE kó èrè òjò tíwọ́n fi...

Láti ọdún 1949, ìgbà tí orílẹ̀-èdè náà bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe àkọsílẹ̀ bíìgbà ṣe rí, àwọn onímọ̀ ìjìnlẹ̀ sọ pé òjò yìí àti omi tó jẹ́ kó yawọlé ni ó pọ̀ jù.Àjọ tí a mọ̀ sí National Centre of Meteorology sọ pé òjò náà jẹ́ kí orílẹ̀-èdè náà ní omi.

Ó yẹ kí a tún mọ̀ pé, àwọn tí wọ́n máa ń sọ bí ojú ọjọ́ yóò ṣe rí, lára wọn tí a mọ̀ sí the Global Flood Awareness System , èyí tí European Commission ṣàkóso rẹ̀ sọ pé ìkún omiyóò ṣẹlẹ̀ ní agbègbè náà kì òjò yìí tó rọ̀. “Ohun tí wọ́n ní Dubai ṣe yìí lè fa ikun omi, gẹ́gẹ́bí a ṣe mọ̀ péìdí tí àwọn ènìyàn ṣe máa ń fà òjò tipátipá ni pé kí òjò lè rọ̀ níàwọn agbègbè tí òjò kò sí tàbí tí òjò kò fi bẹ́ẹ̀ ń rọ̀,” Ogunwumiló sọ bayii.

Gloria Okafor, olùkọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga ní Nigerian Maritime University, ní ìpínlẹ̀ Delta, sọ pé kii se nǹkan tí wọ́n ní Dubai ṣeni ó fa òjò yìí.

 

Thank you for your comment. Your comment will be published after being reviewed.
Please try again later.
We have summarized this news so that you can read it quickly. If you are interested in the news, you can read the full text here. Read more:

 /  🏆 2. in NG

Nigeria Latest News, Nigeria Headlines

Similar News:You can also read news stories similar to this one that we have collected from other news sources.

Ǹjẹ́ ààrẹ orílẹ̀ èdè Senegal sọ pé ìwà orílẹ̀ èdè Faransé sí Senegal kò dára?Nigeria's independent online newspaper
Source: thecableng - 🏆 2. / 80 Read more »

Kwara United shun Sallah, prepare for Gombe United matchDesperate to avoid relegation from the Nigeria Premier Football League (NPFL) this season, Kwara United Football Club did not join other Muslims in the Eid Fitri celebrations. Rather, they continued with their intensive training sessions ahead of their next game against Gombe United in Gombe.
Source: GuardianNigeria - 🏆 1. / 94 Read more »

Plateau United Looks to End Slump Against Doma UnitedPlateau United, after suffering three successive losses, aims to break their losing streak against Doma United. Meanwhile, league leaders Enugu Rangers seek to extend their unbeaten run in Katsina.
Source: TheNationNews - 🏆 6. / 69 Read more »

Amfani da fasahar kirkirar ruwan sama ne ya janyo ambaliyan ruwa a Dubai?Labarai da dama a shafukan sada zumunta na cewa amfani da fasahr kirkirar ruwan sama wanda ake kira 'cloud seeding' ne ya janyo ambaliyar ruwan da a ka yi a United Arab Emirates (UAE).
Source: thecableng - 🏆 2. / 80 Read more »

‘400 aircraft gates, five runways’ -- Dubai to build 'world's largest’ airport terminal at $34.8bnThe United Arab Emirates (UAE) has announced plans to build a new passenger terminal at the Al Maktoum International Airport.
Source: thecableng - 🏆 2. / 80 Read more »

‘400 aircraft gates, five runways’ -- Dubai to build 'world's largest’ airport terminal at $34bnThe United Arab Emirates (UAE) has announced plans to build a new passenger terminal at the Al Maktoum International Airport.
Source: thecableng - 🏆 2. / 80 Read more »