Amófin sọ pé ibanibimọ lòdì sí òfin ní Nàìjíríà. Ṣé òótọ́ ni?

  • 📰 thecableng
  • ⏱ Reading Time:
  • 54 sec. here
  • 2 min. at publisher
  • 📊 Quality Score:
  • News: 25%
  • Publisher: 80%

Nigeria Headlines News

Nigeria Latest News,Nigeria Headlines

Sonnie Ekwowusi, amòfin tí ó tún máa ń jà fún ẹ̀tọ́ àwọn ènìyàn, sọ pé bíbá ẹlòmíràn bímọ tàbí ìbáẹlòmíràn-bímọ (surrogacy) jẹ́ nǹkan tó lòdì sí òfin ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ó sọ ọ̀rọ̀ yìí ní ọjọ́ kejilelogun, oṣù kẹrin, ọdún 2024, nígbà tí wọ́n ń fi ọ̀rọ̀ wa lẹ́nu wò lórí ètò kan tí a mọ̀ sí the Morning Show lórí ẹ̀rọ amóhunmáwòrán Arise Tv.

Amòfin yìí tọ́ka sí apá ọgbọ́n, abala kìíní Òfin ẹ̀tọ́ ọmọdé láti fi kin tàbí ti ọ̀rọ̀ rẹ̀ lẹ́yìn.Apá kẹta òfin kan náà sọ pé ìjìyà àtìmọ́lé ọdún mẹwa ló wà fún ẹni tí ó bá tàpá sí abala Kínní òfin yìí. Abánibímọ yìí máa lóyún ní ọ̀nà ìlóyún ìmọ̀ sayẹnsi . Tí a bá fẹ́ ṣe eléyìí, a máa mú ẹyin obìnrin, a máa loo pọ pẹlu nǹkan ọmọ ọkùnrin-spaamu , eléyìí ló máa di ọmọ.

Ní ọdún 2016, àwọn asòfin kan ṣe àgbékalẹ̀ ètò tó lè di òfin tí a lè fi da rí lílo tẹkinọlọji láti ran ènìyàn lọ́wọ́ láti bímọ níwájú ilé ìgbìmọ̀ asòfin. Àmọ́ kò tíì di òfin.

 

Thank you for your comment. Your comment will be published after being reviewed.
Please try again later.
We have summarized this news so that you can read it quickly. If you are interested in the news, you can read the full text here. Read more:

 /  🏆 2. in NG

Nigeria Latest News, Nigeria Headlines

Similar News:You can also read news stories similar to this one that we have collected from other news sources.

Lawyer claim sey surrogacy dey illegal for Naija. Na true?Sonnie Ekwowusi, one human rights lawyer, tok sey surrogacy for Nigeria na criminal offence wey dey punishable by di law.
Source: thecableng - 🏆 2. / 80 Read more »

Nwányị̀ íburu íbè yá áfọ́ ímé ò mègìdèrè ìwú Naijiria?Sonnie Ekwowusi, onye ọka ikpe nkwado ikike mmadụ, kwuru na nwanyị iburu íbè yá afọ ime, nke bekee na-akpọ surrogacy, bụ omume iwu Naijiria megidere.
Source: thecableng - 🏆 2. / 80 Read more »

Wani lauya yace mace ta daukan ma wata matar ciki karya doka ne a Najeriya. Gaskiya ne?Sonnie Ekwowusi, wani lauya, yace mace ta daukan ma wata matar ciki karya doka ne a Najeriya.
Source: thecableng - 🏆 2. / 80 Read more »

FACT CHECK: Lawyer claims surrogacy is illegal in Nigeria. How true is this?Donnie Ekwowusi, a human rights lawyer, has claimed that surrogacy in Nigeria is a criminal offence punishable by the law.
Source: thecableng - 🏆 2. / 80 Read more »

Fídíò tí àwọn ènìyàn pín tí ó ṣe àfihàn ilé olókè tó ga gan-an kò ní ohunkóhun ṣe pẹ̀lú ìṣẹlẹ (earthquake) tí ó ṣẹlẹ̀ ní orílẹ̀ èdè TaiwanÀwọn ènìyàn kan ti sọ pé Fídíò kan tí ó ṣe àfihàn àwọn ilé tó ga gan-an ní nǹkan ṣe pẹ̀lú ìṣẹlẹ tó kọlu orílẹ̀-èdè Taiwan
Source: thecableng - 🏆 2. / 80 Read more »

Nwányị̀ íburu íbè yá áfọ́ ímé ò mègìdèrè ìwú Naijiria?Sonnie Ekwowusi, onye ọka ikpe nkwado ikike mmadụ, kwuru na nwanyị iburu íbè yá afọ ime, nke bekee na-akpọ surrogacy, bụ omume iwu Naijiria megidere.
Source: thecableng - 🏆 2. / 80 Read more »