Ládọjà àtàwọn afọbajẹ nílùú Ìbàdàn kò fìmọ̀ sọ̀kan lórí ọ̀rọ̀ Olúbàdàn

  • 📰 TheNationNews
  • ⏱ Reading Time:
  • 30 sec. here
  • 2 min. at publisher
  • 📊 Quality Score:
  • News: 15%
  • Publisher: 69%

Nigeria Headlines News

Nigeria Latest News,Nigeria Headlines

The Nation Newspaper Ládọjà àtàwọn afọbajẹ nílùú Ìbàdàn kò fìmọ̀ sọ̀kan lórí ọ̀rọ̀ Olúbàdàn

Ṣe ni ọrọ tun gba ọna mii-ii yọ lori ati yan Olubadan tuntun fun ilu Ibadan, Ọba Owolabi Ọlakulẹhin, nigba ti Ọtun Olubadan, to tun jẹ gomina tẹlẹ nipinlẹ Ọyọ,Oloye Raṣidi Ladọja atawọn afọbajẹ yooku kuna lati kọwọ bọwe adehun lati yanju igbesẹ ọlọbade.

O sọ pe “ Emi pẹlu awọn igbimọ Olubadan ti jọ jokoo papọ, a si ti sọrọ, a si ti gba lati gbe ẹjọ kuro ni kootu.“Mo gbọ pe wọn ti bẹrẹ si nii kọwọ bọwe adehun, lẹyin ti gbogbo wọn ba ṣetan,emi naa yoo waa kọwọ bọwe ni ọna ọdọ mi, bilẹ ọjọ keji ba si ti n mọ, a n lọ si kootu lati lọọ pe ẹjọ pe a o ṣe mọ.

Lara awọn ti wọn wa nibi ipade to waye ni afin Olubadan ni Ọja’ba ni Osi Balogun, Ọba Lateef Gbadamọsi Adebimpe; Aṣipa Olubadan, Ọba Abiọdun Kọla-Daisi; Aṣipa Balogun, Kọla Adegbọla; Ẹkẹrin Balogun, Ọba John Isioye-Dada ati Ẹkaarun Olubadan, Ọba Adebayọ Akande.

 

Thank you for your comment. Your comment will be published after being reviewed.
Please try again later.
We have summarized this news so that you can read it quickly. If you are interested in the news, you can read the full text here. Read more:

 /  🏆 6. in NG

Nigeria Latest News, Nigeria Headlines

Similar News:You can also read news stories similar to this one that we have collected from other news sources.

Olubadan: Ibadan elders wade in on Ladoja, Obas feudThe Nation Newspaper Olubadan: Ibadan elders wade in on Ladoja, Obas feud
Source: TheNationNews - 🏆 6. / 69 Read more »

Ibadan elders move to settle Ladoja, Obas’ rift over Olubadan stoolFacts have emerged that some eminent elders in Ibadanland have met former Governor Rashidi Ladoja, who is also the Otun Olubadan
Source: GuardianNigeria - 🏆 1. / 94 Read more »

Olubadan: Ibadan elders meet Ladoja, wade in to prevent looming crisisProminent indigenes of Ibadan, the Oyo State capital, have met a former governor of the state, Senator Rasidi Adewolu Ladoja, over the crisis between him (Ladoja) and some High Chiefs who have been promoted to the status of Obas in the ancient city.
Source: DailyPostNGR - 🏆 11. / 59 Read more »

Olubadan: Ladoja faults Ajibola on Olakulehin’s health statusThe Nation Newspaper Olubadan: Ladoja faults Ajibola on Olakulehin's health status
Source: TheNationNews - 🏆 6. / 69 Read more »

Mogajis meet Ladoja, seek Olubadan’s speedy coronationThe Nation Newspaper Mogajis meet Ladoja, seek Olubadan’s speedy coronation
Source: TheNationNews - 🏆 6. / 69 Read more »

New twist to Olubadan as kingmakers, Ladoja disagreeThe Nation Newspaper New twist to Olubadan as kingmakers, Ladoja disagree
Source: TheNationNews - 🏆 6. / 69 Read more »