Káyọ̀dé Fáyẹmí àti Afẹ́ Babalọlá: Ó yẹ ẹni gbogbo kó dín owó aró kù kò yẹ atọ̀ọ́lé

  • 📰 TheNationNews
  • ⏱ Reading Time:
  • 67 sec. here
  • 3 min. at publisher
  • 📊 Quality Score:
  • News: 30%
  • Publisher: 69%

Nigeria Headlines News

Nigeria Latest News,Nigeria Headlines

The Nation Newspaper Káyọ̀dé Fáyẹmí àti Afẹ́ Babalọlá: Ó yẹ ẹni gbogbo kó dín owó aró kù kò yẹ atọ̀ọ́lé

L aipẹ yii ni ede-ai-yede waye laarin gomina ana nipinlẹ Ekiti, Ọmọwe Kayọde Fayẹmi ati agba ọjẹ ninu imọ ofin ati oludasilẹ Yunifasiti Afẹ Babalọla, Aarẹ Afẹ Babalọla nipa ọrọ ti baba yii sọ nigba to n ṣe agbeyẹwo awọn gomina to ti jẹ ni ipinlẹ Ekiti.

Yoruba bọ wọn ni o yẹ ẹni gbogbo ko din owo aro ku, ko yẹ atọọle. Ko yẹ ko jẹ iru Fayẹmi ni yoo tabuku baba Afẹ, ti Oke lbadan yoo ba gba maalu, ki i ṣe ẹnu alagbaro ni wọn yoo ti gbọ ọ. Ni ilẹ oni to mọ, ko si ẹni to le gbagbe ipa ribiribi ti Afẹ Babalọla ko nipa dida ipinlẹ Ekiti silẹ, gbogbo ohun to wa ni ikapa rẹ lo ṣe to si lo lati jẹ ki ipinlẹ Ekiti waye eyi ti Fayẹmi ni anfani lati ṣe gomina rẹ. Inu igbo ni ọbọ Fayẹmi wa nigba ti ewurẹ Babalọla ti n ṣogo ninu ile.

Gẹgẹbi oniroyin onitọpinpin fun ọpọlọpọ ọdun, oju tole, bẹẹ loju toko, bẹẹ ni itan ko ni i gbagbe awọn iṣẹ akanṣe ti ijọba Fayẹmi pati bii aṣọ to gbo, ti ọpọlọpọ owo gọbọi si wọlẹ si i. Ṣugbọn eleyii ki i ṣe ohun a mu jiroro ni akoko yii, bi ko ṣe ọjọ mi-in ọjọ’re. Ninu iwoye wọn nipa gbọn mi si omi ko to yii to wa laarin awọn ọmọ Ekiti meji yii, ẹgbẹ kan ti ki i ṣe tijọba ti wọn pe ara wọn ni ‘Ekiti Patriotic Consultative Forum’ sọ pe ede agọ gbaa ni Fayẹmi pe lati sọ pe ọjọ ori n da baba Afẹ Babalọla laamu ati pe ohun lo jẹ ko sọ ohun to sọ.

Bo tilẹ jẹ pe ẹgbẹ yii sọ pe ki Fayẹmi tọrọ aforiji fun aṣiṣe to ṣe, ṣugbọn Yoruba sọ pe wọn ni ki oro ma sọko mọ, ṣugbọn eyi to wa lọwọ rẹ yii nkọ? Ohun to daju ni pe ọmọde to n jẹ eewọ, awọn baba wa ni ko mura si i ko maa jẹ ẹ, to ba ya ohun to n bini ko ni i ṣalai bini.

 

Thank you for your comment. Your comment will be published after being reviewed.
Please try again later.
We have summarized this news so that you can read it quickly. If you are interested in the news, you can read the full text here. Read more:

 /  🏆 6. in NG

Nigeria Latest News, Nigeria Headlines

Similar News:You can also read news stories similar to this one that we have collected from other news sources.

The constitutionality of death penalty: Need to amend the law, by Afe BabalolaA Nigerian newspaper and Online version of the Vanguard, a daily publication in Nigeria covering Nigeria news, Niger delta, general national news, politics, business, energy, sports, entertainment, fashion,lifestyle human interest stories, etc
Source: vanguardngrnews - 🏆 5. / 75 Read more »

The constitutionality of death penalty: Need to amend the law (2), by Afe BabalolaA Nigerian newspaper and Online version of the Vanguard, a daily publication in Nigeria covering Nigeria news, Niger delta, general national news, politics, business, energy, sports, entertainment, fashion,lifestyle human interest stories, etc
Source: vanguardngrnews - 🏆 5. / 75 Read more »

Retrace your steps, Afe Babalola tells secessionistsThe Nation Newspaper Retrace your steps, Afe Babalola tells secessionists
Source: TheNationNews - 🏆 6. / 69 Read more »

Afe Babalola Advocates Against Division of NigeriaAare Afe Babalola, the founder of Afe Babalola University (ABUAD), advocated against the division of Nigeria into several small nations on Monday, saying that its enormous number of tribes and languages are not responsible for underdevelopment.
Source: channelstv - 🏆 7. / 63 Read more »

Afe Babalola Laments Effects Of Economic Hardship On LawyersThe Latest News from Nigeria and Around the World
Source: channelstv - 🏆 7. / 63 Read more »

2024 Student Loans ACT: Discriminatory and unconstitutional, by Afe BabalolaA Nigerian newspaper and Online version of the Vanguard, a daily publication in Nigeria covering Nigeria news, Niger delta, general national news, politics, business, energy, sports, entertainment, fashion,lifestyle human interest stories, etc
Source: vanguardngrnews - 🏆 5. / 75 Read more »